E lagbara lyrics By Toluwanisings

 

E lagbara lyrics By Toluwanisings


Lyrics: E Lagbara by Toluwani Sings
Mokan sha mo wipe E’lagbara
Okan ye mi ni wipe mi o le te o
Eni ti mo gbojule kii se niyan
Ti o fi seke laye iya o le jemi

SORO SOKE!
Mokan sha mo wipe E’lagbara
Okan ye mi ni wipe mi o le te o
Eni ti mo gbojule kii se niyan
Ti o fi seke laye iya o le jemi Ah! Ah! Ah! Ah!.
MA GBO!

To ba je towo
Baba mi lo da
Agbara nko
Iyen koja radarada
Mo kan sha mo wipe e tobi o
Kaka kin te
Esu fun rare lo ma te.
SORO SOKE!
Mokan sha mo wipe E’lagbara!O Dami loju.
Okan ye mi ni wipe mi o le te o I have assurance in Jesus
Eni ti mo gbojule kii se niyan
Ti o fi seke laye Laye Laye
Iya o le jemi!!

Piano Playing

APEKE Baye tile leeee beni
Bogun tile po fun ogo mi.
Emi reni gbojule ti kii dani
Aja mi ti leni leyin aapogo.
Igbojule mi ninu re daju
Iwo loni gbogbo aye ni ikawo re
Esu o le tan mi tori moni o lolorun
O ki n se niyan ti o seke lailai

Mokan sha mo wipe E’lagbara!Agbara re po Gan.
Okan ye mi ni wipe mi o le te o!Oye mi wipe Mo le ni to ju aye lo.
Eni ti mo gbojule kii se niyan Eh eh eh.
Ti o fi seke laye iya o le jemi O’le seke o.

E ti gbo odami loju
Otun ju ada lo
Your grace is there for me
I cannot be disgrace
Awa ni iran ti ayan olu alufa
Enipe jesu mi o ki n segbe omo aye

PA ARI WO SE!
Mokan sha mo wipe e lagbara!Eri tun de Mountain.
Okan ye mi ni wipe mi o le te o!So Lori kekele so ni petele.
Eni ti mo gbojule kii se niyan!La timu okan le.
Ti o fi seke laye!Kin se niyan rara o ko le seke lai lai.
Iya o le jemi

Ah! Ani e tobi edara olorun temi
Your grace is so great baba mi Jesu wa o
Araba ribiti arugbo ojo
Osomi dalase ori o fola yi mi ka.
Mokan sha mo wipe e tobi o.
A nfani nla loje lati je omo re

SORO SOKE!
Mokan sha mo wipe E’lagbara
Okan ye mi ni wipe mi o le te o
Eni ti mo gbojule kii se niyan!A ko dami ri.
Ti o fi seke laye iya o le jemi!Ko le doju timi o sure fun mi.
Mokan sa mo wipe E’lagbara!Ko dami ri ko doju timi.
Okan ye mi ni wipe mi o le te o!Ore kankan soso ti Mo ni ni ye n o.
Eni ti mo gbojule kii seniyan Ah! Egbon le dani Aburo.
Ti o fi seke laye iya o le jemi!Won le salo
Olorun ni kan ni o le dani Lola

PIANO PLAYING

End of   E lagbara lyrics By Toluwanisings

E lagbara lyrics By Toluwanisings


 E lagbara lyrics By Toluwanisings

 E lagbara lyrics By Toluwanisings

 E lagbara lyrics By Toluwanisings

 E lagbara lyrics By Toluwanisings

 E lagbara lyrics By Toluwanisings

 E lagbara lyrics By Toluwanisings