EROOMI - Emi Mimo lyrics

EROOMI -  Emi Mimo lyrics


Jesu Jesu jeeeessuuu

emi mimo emi olorun oba

emi inu baba mi,emi to gbe

ninu eni to gbe dide mi

chants

mo fe ohhh emi mimo

mo ni lore emi mimo

akunwosile re ohhhhh ni mo fe ohhh

ma sun ninu mi ohhh

pepe mi o gbodo Kun

akunwosile re ohhhhhhh

ni mo fe ohhh

mo fe ooo emi mimo

e lo mi ni lore

chants

shebi wo ni pepe mi Jesu

Iwo ni pepe mi apata ti mo gbe

to mo ti gba agbara

ibi egbin o gbodo yii panashaga agbere (chants) pepe mi o gbodo Ku chants

o login Ara mi ni pepe re

pepe ti gbogbo aye pe 

End of EROOMI -  Emi Mimo lyrics

EROOMI -  Emi Mimo lyrics



Profile of Eroomi

Full Name: Rahmat Eroomi Akintunde

Stage Name: Eroomi

Nationality: Nigerian

Genres: Gospel, Contemporary Worship, Nigerian Gospel, Chant

Roles: Singer, songwriter, worship leader

🌱 Beginnings & Ministry

Eroomi began her journey singing in church and later grew into a worship ministry that blends spontaneous praise, prophetic chants, and deep worship expressions.

She holds a degree in Business Administration and is known as a worship intercessor with a heart for intimacy with God.


EROOMI -  Emi Mimo lyrics

EROOMI -  Emi Mimo lyrics

EROOMI -  Emi Mimo lyrics

EROOMI -  Emi Mimo lyrics



Search This Blog

Featured Post