Alujanjankijan lyrics By Sola Allyson Ft. Adekunle Gold
Iya iya ta’kun wa’le, Alujanjankijan
Iya iya ta’kun wa’le, Alujanjankijan
E ma f’omo sile fun iya je, Alujanjankijan
Eni to bimo loye ko wo’mo, Alujanjankijan
(Sola Allyson)
Bami nan momi ye ko de’nu olomo
Oju merin lon bimo sugbon igba oju lon w’omo
Omo tao ko, a gbe ile ta ko ta
Omo tao ko, a ko eso tani ta
Omo nigbeyin, Omo lola, Omo lola
Omo niyi, Omo lade, Omo lewa, Omo leso oo
Oda bioda, o le da
O san bio san, a de san
Igboya ati adura ni yio gba
Yio da
Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
E ma f’omo sile fun iya je, Alujanjankijan
Eni to bimo loye ko wo’mo (e tomo), Alujanjankijan
(Adekunle Gold)
Ori funmi l’omo rere bi ti Samuel o
Won kosa fun o gbe eko o
If you spare the rod you go spoil the child I hope you know ooo
Train them with the love of God I beg oooo
Tori alaigboran omo, asa ni
Agba o jo won loju, asa ni
Agbaya ni o da, asa ni
Alaigboran omo o, omo ni
Won le d’eyan lola, omo ni
Ta ba ko won dada, omo ni
Won le d’eyan lola, omo ni
Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
Eni to bimo lo ye ko w’omo, Alujanjankijan
E ma f’omo sile fun iya je, Alujanjankijan
Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
E ma f’omo sile fun iya je, Alujanjankijan
Eni to bimo lo ye ko w’omo, Alujanjankijan
E ma f’omo sile fun iya je, Alujanjankijan
Iya baba ta’kun wale, Alujanjankijan
Kekere lati npa eka iroko
To ba dagba tan ebo ni yio ma gba
Ohun ta bi fi sile l’ewure ngbe
K’ewure aye ma ma gbe wa l’omo lo
Omo ta o ro ekun aye a gbe lo
K’ekun aye ma ma gbe wa l’omo lo
Iya Iya ta’kun wale, Alujanjankijan
Iya Iya ta’kun wale, Alujanjankijan
End of Alujanjankijan lyrics By Sola Allyson Ft. Adekunle Gold
Alujanjankijan lyrics By Sola Allyson Ft. Adekunle Gold
Alujanjankijan lyrics By Sola Allyson Ft. Adekunle Gold
Alujanjankijan lyrics By Sola Allyson Ft. Adekunle Gold
Alujanjankijan lyrics By Sola Allyson Ft. Adekunle Gold
Other lyrics
Malaika x Fridayy lyrics ft. Fridayy - Teni
Up To Something Lyrics by ONE HOUSE, UPPERRROOM ft. Rudy Villarreal, Skylar
Goodness of God lyrics by Cece Winans
I AM A SOLDIER Lyrics by Ebuka Songs
TESTIMONY JAGA – BURST THEIR BRAIN LYRICS
OUR MISSION
Our MISSION is to spread the gospel through the promotion
of Gospel music, Ministries, Music concerts and more.
The idea to support and promote Music Events,
Church Revivals and similar activities
within the Christian faith is what we share
*COPYRIGHT DISCLAIMER*
We do not own the Lyrics for any of the songs or the images featured on this website.
All Lyrics rights belong to its original owner/owners.
No copyright infringement is intended.
We STRONGLY advice you purchase tracks from outlets provided by the original owners
Contents here are for promotional purposes only.
Please Add a comment below if you have any suggestions
Thank you & God Bless you!
All Song Lyrics are the property and Copyright of the Original Owners
Songs and Images here are For Personal and Educational Purpose only