EmmaOMG - B'aye Ba N Fa Mi ft. The OhEmGee Choir
...
b'aye ba nfa mi pelu ogo re
kò séwu ọmọ Ọlọrun ni mi
Owo agbara Re yo di mi mi
L'ojo àyè mi gbogbo..
chorus:..Mo l'ore to npese f'aini
Gbogbo
Mo nile kan loke orun gíga
Nje nitori ìdí eyi na ni
Emi ṣe nko halleluyah
Emi ko jẹ gbagbe pe l'ori gi
Ni ọmọ Ọlọrun gbè ku fún mi
kò saiku lati gb'okan mi là
kò tun sona miran mo ...hhhhmmmm
aaaaaaiiiiii
Ng o joloto s Olúwa Ọba mi
Ng o ma kọrin yin sì nigbagbogbo
Mo mo pè nikehin..Òún yo gbà mi
Lati ma bà gbe titi
End of EmmaOMG - B'aye Ba N Fa Mi ft. The OhEmGee Choir
EmmaOMG - B'aye Ba N Fa Mi ft. The OhEmGee Choir
EmmaOMG - B'aye Ba N Fa Mi ft. The OhEmGee Choir
EmmaOMG - B'aye Ba N Fa Mi ft. The OhEmGee Choir
EmmaOMG (stylized as EmmaOMG) is a Nigerian gospel singer, comedian, content creator, and worship leader. He is especially known for blending high-energy Yoruba praise, comedy, and creativity to spread the gospel of Christ.
Quick Facts about EmmaOMG
Full Name: Emmanuel Iren Omogbai (popularly known as EmmaOMG)
Nationality: Nigerian
Occupation: Gospel singer, comedian, content creator
Genres: Gospel, Yoruba praise, contemporary worship
Group: Leader of the Hallelujah Challenge-inspired band often referred to as “The OAU Angels” or his music crew
Other lyrics
David Dam - Father of Mercy lyrics (Live)
kaestrings - Desire (Live) lyrics
GRACE OLUWALOJU & kaestrings - The Glory (Live) lyrics