Lyrics
Mimo Mimo Mimo solo du mare
oju elese kole ri ogo re+
Mimo Mimo Mimo solo du mare
oju elese kole ri ogo re
Mimo Mimo Mimo solo du mare
oju elese kole ri ogo re
Mimo Mimo Mimo solo du mare
oju elese kole ri ogo re
Mimo Mimo Mimo solo du mare
oju elese kole ri ogo re
Mimo Mimo Mimo solo du mare
oju elese kole ri ogo re
Mimo Mimo Mimo solo du mare
oju elese kole ri ogo re
Mimo Mimo Mimo solo du mare
oju elese kole ri ogo re
Baba alagbara baba imole
Gbogbo ope gbogbo ogo ni fun oruko re
Majobalo oluwa majobalo oluwa
Majobalo oluwa ko si elomiran leyin re
Oba takole roloye alagbara takole segun ni
ijoba re dun mo wa odun mo wa
Majobalo majobalo majobalo
Majobalo oluwa majobalo oluwa
Majobalo oluwa ko si elomiran leyin re
Oba takole roloye alagbara takole segun ni
ijoba re dun mo wa odun mo wa yeye o
Majobalo majobalo majobalo oluwa
Majobalo oluwa majobalo oluwa
Majobalo oluwa ko si elomiran leyin re
Oba takole roloye alagbara takole segun ni
ijoba re dun mo wa odun mo wa
Majobalo majobalo majobalo
Ola le wo laso ogo laso ileke
Iyin le gun lesin awa maridi o olodumare
Ola le wo laso ogo laso ileke
Iyin le gun lesin awa maridi o olodumare
Inu mi du ayo mi kun nitori mo moyin
Ola le wo laso ogo laso ileke
Iyin le gun lesin awa maridi o olodumare
Ola le wo laso ogo laso ileke
Iyin le gun lesin awa maridi o olodumare
Iyin le gun lesin awa maridi o olodumare
Lati inu okan wa lawa lawo le
Iyin le gun lesin awa maridi o olodumare
Ao ri yin sugbon a mo pe ew larin wa
Ao ri oju yin o sugbon awo oju yin fun anu to po
Ao mola ti owo yin ko sugbon a ri owo yin lara wa
Kabiyesi wa gbola re kabiyesi wa gbola re
Iwo nikan ma ni iwo lo da ohun gbogbo
Gbogbo ola gbogbo ogo gbogbo iyin gbogbo agbara iwo loni
Ma sola re lo ninu ola ma sola re lo ninu ola ma sola re lo
Kabiyesi wa gbola re kabiyesi wa gbola re
Olorun ti gbeni ga olorun ti fini mona olorun ti toni sona mo se ba re
Oba sere ma se bi oba ti fayo mo nu re
Oloju anu ni o baba to fanu han simi
Ma so la re kabiyesi wa gbola re
M sola re lo kabiyesi wa gbola re
Wa gbola re oba oke oba gegere oba eranko inu gbo
Na sola re lo awon orun soro ise re kabiyesi ma sola re
Ofurufu soro ise re kabiyesi wa gbola re
Ojo de ojo fohun igba de igba fi ogo re han
Kabiyesi wa sola re lo kabiyesi wa sola re lo
Lese ite re ni la wole amope wa
Amu iyin wa aforibale fun o baba
Iwo nikan logo to si iwo nikan lola tossi oo
Baba talo dabire
Talaba fi owe talo le ba o jogba
Talaba fi owe talo le ba o jogba
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Talaba fi owe talo le ba o jogba
Talaba fi owe talo le ba o jogba
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Talaba fi owe talo le ba o jogba
Talaba fi owe talo le ba o jogba
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Talaba fi owe talo le ba o jogba
Talaba fi owe talo le ba o jogba
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Lati inu okan mi wa mo fi ope fu oruko re
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
Olorun to ju olorun lo talaba fi o we
You are the reason why we are singing jehovah
You are the most high God
For you are the reason why we are living jehovah
You are the most high God
Jehovah you are the most high
Jehovah you are the most high God
Jehovah elohim jehovah ralpha
You are the most high
Jehovah you are the most high God
Enu wa yo ma ko rin iyin re nigba gbogbo
You are the most high
Iyin re yi aiye ka
You are the most high God
Oba alanu oba olori ofe jehova
You are the most high
Oluwa iwo lo ye lati gba gbogbo ogo
You are the most high God
Bi o ba si iwo nibo ni emi gangan o ba wa
You are the most high
Oba to fowo agbara gba mi lowo alagabra to fowo agbara ji ni niya
You are the most high God
Eh jehovah jehovah moyin oruko re
You are the most high
Baba alanu mi baba oloore mi
You are the most high God
Iyin re yi aiye ka iyin re gba gbgbo okan mi
ou are the most high
Arugbo ojo adagba ma tepa baba alaanu
You are the most high God
Jehovah you are the most high
Jehovah you are the most high God
You are the reason why we are living why we are singing
You are the most high
Nitori re lasen rin lasen yan fandan
You are the most high God
Ife re nikan lo gbe wa ro jehovah wa gbope oo a gbayin wa gbogo
You are the most high God
Jehovah you are the most high
Jehovah you are the most high God
Jehovah raphe jehovah shalom jehovah elohim
You are the most high
The mighy man in battle we praise you
You are the most high God
Olorun mi iwo ni ma sin titi aiye mi amin o
Eje mi ni yen baba
Lojo mo ri je ee oluwa lati odo re wa
Lojo mo ri mu o oluwa latodo re bo
Bi mo ti rayo se iwo lo fun mi layo se
Oluwa latodo re wa
Bi mo ti rebun lo iwo lo funmi lebun lo
Oluwa latodo bo baba baba o
Olorun mi iwo ni ma sin titi aiye mi amin
Ore ofe re to oto fun mi o
Emi le se ohun gbogbo
Emi yio sin o titi aiye mi baba
Eni to nigba mi iwo ni ma sin titi aiye mi amin o
Olufuni lebun to fun mi lebun oshe baba
Lojo mo ri je oluwa latodo re
Lojo morimu oluwa latodo re bo
Bi mo ti lo bi mo ti bo ti mo yan fandafanda
Oluwa lotodo re wa
Bi mo ti rayo se ti mo rogo iwo lo fun mi logo lo
Olorun mi iwo ni ma sin titi aiye mi amin
End of SOLA ALLYSON – MIMO Lyrics
SOLA ALLYSON – MIMO Lyrics
SOLA ALLYSON – MIMO Lyrics
SOLA ALLYSON – MIMO Lyrics
SOLA ALLYSON – MIMO Lyrics
SOLA ALLYSON – MIMO Lyrics
SOLA ALLYSON – MIMO Lyrics
SOLA ALLYSON – MIMO Lyrics
SOLA ALLYSON – MIMO Lyrics
SOLA ALLYSON – MIMO Lyrics
SOLA ALLYSON – MIMO Lyrics