Information
Album:ÌGBÒWÓ ÈDÁ
Genre:Gospel
Year of Release:2023
Lyrics
Ise Owo Re - Tope Alabi
...
Igba to mu omo Israeli
loko eru
Ao le sopee
O mo won akan okun pupa
Igba ti Danieli rufin
Oba lojo si
O ku ku mo pe
Iho kiniun ni
Won o sooosii
Omo eberu metta ko
Won o fori bale oo
Oo shaimo won a ju won
Si inu ina o
Iwo to o pin
Okun niya
Iwo to pa eyin
Kiniun mo
Iwo naa lo sikerin
Ninu ina ileru aaa
Eru re maa to ba ooo
Olorun ogooo
Eru re nba mi oooo
Ise owo re nba mi leru
…
Ise owo re nba mi leru ooo
Oun to mo
Iwo gangan la
momo tan olodumare
…
Ise owo re nba mi leru
O nba mi leru
Igba ti lasaru saisan
Won ranse si o o
Ao le pe oomo pe
Yi o la iku lo ni
Igba ti Abrahamu fe sarah
Ni wundia
Okuku mo pe
Oo fojo Igbo won dara ire
Igba to ni ki abrahamu
Fi isaaki rubo fun o oo
Sebi iwo naa lo fi
Agbo eran dipo omo fun
Iwo to ji oju lasaru
Iwo to fomo da arugbo lola
Iwo to fi igboran
Fi agbo eran dipo
Omooo
Eru re to ba o
Olorun Ogo oo
Eru re nba emi oooo
Ise owo re nba mi leru
…
Ise owo re nba mi leru ooooo
Iwo to ni iku ati iye
O mora e awa ni o ye eee
Oluda
Olubi
Awogba arun ma gbeje
Ayiwo ojo pada eeee
Oun to wun o loun se
Igba ti josefu lala
Ko ba ti roo
Ao le pe oomo pe
Awon egbon re yio seke ta
Igba toba laala eru
To n wa eni ti o roo
Okuku mo pe elewon josefu
Ni yio tu fun oba
Iwo naa lomo Pe josefu
Aa pada wa bo gbogbo ebi e
Emi o ri oun to seyin re ri
Aditu oba ogo
O fi Iran ogo han josefu
O tun mu oba laala aditu
Iwo to fi elewon se edidiyan
Eru re to ba oooo
Ijinle nla ni o
aaaaa
Ise owo re nba mi leru
Ise owo re nba mi leru
Iwo lo fope damu ologbon
O fi alailagbara damu alagbara ooo
A fori sofa nitori ogo
Moyanmoyan ni o
Too moo yan saye to yan to yanju
Olorun nla
O n ba mi leru ooo
O ran isiah to Ezekiah lo
Oyeku ni o
O gbeyin boro yo
O gba satani laye ni Ile jobu
Okuku mo pe ilopo loofi di
Bo ti je gaan niyen
Asiri lojeee
Bo ti ri gaan niyen
Iwo ni ijinle oooo
O gbona eburu fa kayefi eee
O buse gada soro Ana di
bami koju o to mo o
ni aye sope ko le se tooo tele
O wa ko ile alaruru ni igbeyin
Eni ore po fun tori ise ni ijosi oo
O pada wa di olota o
Nitori oro
Iwo to mo opin lati ibere
Eru re nba mi ooo
Eni ti o beru r
Oun to da ju sobia lo
aaa o nba ni leru
…
Olorun amomotan
Ko si amoju loro re ooo
Iwo ganga ni yeee
Olusaju aye de
Oro to wa
Ka to maa soro
…
Ijinle to fi ijinle bora
Ise owo re n ba mi leru
Kayefi nla to n ka ni laya
Ise owo re n ba mi leru
Awari olorun ogo
Ise owo re nba mi leru
Awamaridi onise nla
Ise owo re nba mi leru
Ise owo re n ba mi ooo
Ise owo re nba mi ooo
Ise owo re nba mi leru
…
O bami leru ooo
Eleru niwa ni o
Eleru nise ni o
Iwo leleru loro
Eleru lero oo
Oloro to po
Ay
e owo re
Orun ikawo
Kabiesi ooo
On ba mi leru ooo…
Tags: Tope Alabi - Ise Owo Re Lyrics
Tope Alabi - Ise Owo Re download
OUR MISSION
Our MISSION is to spread the gospel through the promotion
of Gospel music, Ministries, Music concerts and more.
The idea to support and promote Music Events,
Church Revivals and similar activities
within the Christian faith is what we share
*COPYRIGHT DISCLAIMER*
We do not own the Lyrics for any of the songs or the images featured on this website.
All Lyrics rights belong to its original owner/owners.
No copyright infringement is intended.
We STRONGLY advice you purchase tracks from outlets provided by the original owners
Contents here are for promotional purposes only.
Please Add a comment below if you have any suggestions
Thank you & God Bless you!
All Song Lyrics are the property and Copyright of the Original Owners
Songs and Images here are For Personal and Educational Purpose only!