Information
Album:Ebeneseri Wa Re O (Ebenezer)
Genre:Gospel
Year of Release:2023
Lyrics
Ebeneseri Wa Re O (Ebenezer) - Apex Choir
...
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti e ran wa lowo de
Ka’ma jo o kayo ka fogo folu
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti e ran wa lowo de
Ka’ma jo o kayo ka fogo folu
Ebenezeri wa re o
Ema ma se ese
Kima nse nipa agbara
Oluwa loni imo ati oye
ogo ti aye ri to polongo
Tire lo bawase
Orin hallelujah hosanna lo gbenu wa ko
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti e ran wa lowo de
Ka’ma jo o kayo ka fogo folu
Ebenezeri wa re o
Ema ma se ese
Kima nse nipa agbara
Oluwa loni imo ati oye
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti e ran wa lowo de
Ka’ma jo o kayo ka fogo folu
Tags: Ebeneseri Wa Re O (Ebenezer) lyrics - Apex Choir
Ebeneseri Wa Re O (Ebenezer) - Apex Choir